-
1 Sámúẹ́lì 11:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àwọn èèyàn náà wá sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Àwọn wo ló ń sọ pé, ‘Ṣé Sọ́ọ̀lù ló máa jẹ ọba lé wa lórí?’+ Ẹ fi wọ́n lé wa lọ́wọ́, a ó sì pa wọ́n.”
-