4 Síbẹ̀, Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì yàn mí nínú gbogbo ilé bàbá mi láti di ọba lórí Ísírẹ́lì títí láé,+ nítorí ó yan Júdà ṣe aṣáájú,+ nínú gbogbo ilé Júdà, ó yan ilé bàbá mi,+ nínú gbogbo ọmọ bàbá mi, èmi ni ó fọwọ́ sí, láti fi mí jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì.+