-
1 Sámúẹ́lì 13:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àwọn Hébérù kan tiẹ̀ sọdá Jọ́dánì lọ sí ilẹ̀ Gádì àti Gílíádì.+ Àmọ́ Sọ́ọ̀lù ṣì wà ní Gílígálì, jìnnìjìnnì sì ti bá gbogbo àwọn èèyàn tó ń tẹ̀ lé e.
-