ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 14:49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 Àwọn ọmọkùnrin Sọ́ọ̀lù ni Jónátánì, Íṣífì àti Maliki-ṣúà.+ Ó ní ọmọbìnrin méjì; èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Mérábù,+ àbúrò rẹ̀ sì ń jẹ́ Míkálì.+

  • 1 Sámúẹ́lì 18:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Gbàrà tí Dáfídì bá Sọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ tán, Jónátánì+ àti Dáfídì wá di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́,* Jónátánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara rẹ̀.*+

  • 2 Sámúẹ́lì 1:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Dáfídì sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Báwo ni ọ̀hún ṣe rí? Jọ̀ọ́, sọ fún mi.” Ó dáhùn pé: “Àwọn èèyàn ti sá kúrò lójú ogun, ọ̀pọ̀ ló ti ṣubú tí wọ́n sì ti kú. Kódà Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì ọmọ rẹ̀ ti kú.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́