1 Sámúẹ́lì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọmọkùnrin Élì jẹ́ èèyàn burúkú;+ wọn ò ka Jèhófà sí. 1 Sámúẹ́lì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọkùnrin tó mú ìròyìn náà wá sì sọ pé: “Ísírẹ́lì ti sá níwájú àwọn Filísínì, wọ́n sì ti ṣẹ́gun àwọn èèyàn wa lọ́nà tó kàmàmà+ àti pé àwọn ọmọ rẹ méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì ti kú,+ wọ́n sì ti gba Àpótí Ọlọ́run tòótọ́.”+
17 Ọkùnrin tó mú ìròyìn náà wá sì sọ pé: “Ísírẹ́lì ti sá níwájú àwọn Filísínì, wọ́n sì ti ṣẹ́gun àwọn èèyàn wa lọ́nà tó kàmàmà+ àti pé àwọn ọmọ rẹ méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì ti kú,+ wọ́n sì ti gba Àpótí Ọlọ́run tòótọ́.”+