-
1 Sámúẹ́lì 14:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Sọ́ọ̀lù sọ fún àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé: “Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ka iye àwọn èèyàn, kí ẹ sì mọ ẹni tó ti kúrò lọ́dọ̀ wa.” Nígbà tí wọ́n kà wọ́n, wọ́n rí i pé Jónátánì àti ẹni tó ń gbé ìhámọ́ra rẹ̀ kò sí níbẹ̀.
-