-
Ẹ́kísódù 18:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Inú Jẹ́tírò dùn torí gbogbo ohun rere tí Jèhófà ṣe fún Ísírẹ́lì, bó ṣe gbà wọ́n sílẹ̀ kúrò ní* Íjíbítì.
-
-
Ẹ́kísódù 18:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Jẹ́tírò bàbá ìyàwó Mósè wá mú ẹbọ sísun àtàwọn ẹbọ míì wá fún Ọlọ́run, Áárónì àti gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì sì bá bàbá ìyàwó Mósè jẹun níwájú Ọlọ́run tòótọ́.
-