22 Élì ti darúgbó gan-an, àmọ́ ó ti gbọ́ gbogbo ohun tí àwọn ọmọ rẹ̀ ń ṣe+ sí gbogbo Ísírẹ́lì àti bí wọ́n ṣe ń bá àwọn obìnrin tó ń sìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé sùn.+
17 Ọkùnrin tó mú ìròyìn náà wá sì sọ pé: “Ísírẹ́lì ti sá níwájú àwọn Filísínì, wọ́n sì ti ṣẹ́gun àwọn èèyàn wa lọ́nà tó kàmàmà+ àti pé àwọn ọmọ rẹ méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì ti kú,+ wọ́n sì ti gba Àpótí Ọlọ́run tòótọ́.”+