-
1 Sámúẹ́lì 3:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Sámúẹ́lì sùn títí di àárọ̀, lẹ́yìn náà ó ṣí àwọn ilẹ̀kùn ilé Jèhófà. Ẹ̀rù ń ba Sámúẹ́lì láti sọ ìran náà fún Élì.