1 Sámúẹ́lì 16:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bí wọ́n ṣe wọlé, tí ó sì rí Élíábù,+ ó sọ pé: “Ó dájú pé ẹni àmì òróró Jèhófà ló dúró yìí.”