-
1 Sámúẹ́lì 17:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ìgbà tí Sọ́ọ̀lù àti gbogbo Ísírẹ́lì gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Filísínì náà sọ, àyà wọn já, ẹ̀rù sì bà wọ́n gan-an.