1 Sámúẹ́lì 17:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì kóra jọ, wọ́n pàgọ́ sí Àfonifojì* Élà,+ wọ́n sì tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti pàdé àwọn Filísínì. 1 Sámúẹ́lì 17:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Wọ́n wà pẹ̀lú Sọ́ọ̀lù àti gbogbo àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì yòókù ní Àfonífojì* Élà,+ wọ́n ń bá àwọn Filísínì jà.+
2 Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì kóra jọ, wọ́n pàgọ́ sí Àfonifojì* Élà,+ wọ́n sì tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti pàdé àwọn Filísínì.
19 Wọ́n wà pẹ̀lú Sọ́ọ̀lù àti gbogbo àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì yòókù ní Àfonífojì* Élà,+ wọ́n ń bá àwọn Filísínì jà.+