-
1 Sámúẹ́lì 16:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ni Sọ́ọ̀lù bá rán àwọn òjíṣẹ́ sí Jésè pé: “Fi Dáfídì ọmọ rẹ tó wà pẹ̀lú agbo ẹran ránṣẹ́ sí mi.”+
-
-
1 Sámúẹ́lì 16:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Bí Dáfídì ṣe wá sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù nìyẹn, tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìránṣẹ́ rẹ̀.+ Sọ́ọ̀lù wá nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ gan-an, ó sì yàn án pé kó máa gbé ìhámọ́ra òun.
-