-
1 Sámúẹ́lì 16:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Jọ̀ọ́, jẹ́ kí olúwa wa pàṣẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó wà níwájú rẹ̀ pé kí wọ́n wá ọkùnrin tó mọ háàpù ta dáadáa.+ Ìgbàkígbà tí Ọlọ́run bá ti jẹ́ kí ẹ̀mí búburú dà ọ́ láàmú, yóò ta háàpù náà, ara rẹ á sì balẹ̀.”
-
-
1 Sámúẹ́lì 16:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ìgbàkígbà tí Ọlọ́run bá ti jẹ́ kí ẹ̀mí búburú mú Sọ́ọ̀lù, Dáfídì á mú háàpù, á sì ta á, ìtura á bá Sọ́ọ̀lù, ara rẹ̀ á balẹ̀, ẹ̀mí búburú náà á sì fi í sílẹ̀.+
-