1 Sámúẹ́lì 25:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jọ̀wọ́, dárí ìṣìnà ìránṣẹ́bìnrin rẹ jì í, nítorí ó dájú pé Jèhófà máa ṣe ilé tó máa wà títí láé fún olúwa mi,+ nítorí àwọn ogun Jèhófà ni olúwa mi ń jà+ àti pé kò sí ìwà ibi kankan tí a rí lọ́wọ́ rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+
28 Jọ̀wọ́, dárí ìṣìnà ìránṣẹ́bìnrin rẹ jì í, nítorí ó dájú pé Jèhófà máa ṣe ilé tó máa wà títí láé fún olúwa mi,+ nítorí àwọn ogun Jèhófà ni olúwa mi ń jà+ àti pé kò sí ìwà ibi kankan tí a rí lọ́wọ́ rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+