1 Sámúẹ́lì 18:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ni Dáfídì bá sọ fún Sọ́ọ̀lù pé: “Ta ni mí, ta sì ni àwọn ẹbí mi àti ìdílé bàbá mi ní Ísírẹ́lì, tí màá fi di àna* ọba?”+
18 Ni Dáfídì bá sọ fún Sọ́ọ̀lù pé: “Ta ni mí, ta sì ni àwọn ẹbí mi àti ìdílé bàbá mi ní Ísírẹ́lì, tí màá fi di àna* ọba?”+