1 Sámúẹ́lì 2:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ní gbogbo àkókò yìí, ọmọdékùnrin náà Sámúẹ́lì ń dàgbà sí i, ó sì túbọ̀ ń rí ojú rere Jèhófà àti ti àwọn èèyàn.+ 1 Sámúẹ́lì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Sámúẹ́lì ń dàgbà sí i, Jèhófà fúnra rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,+ kò sì jẹ́ kí èyíkéyìí nínú gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ láìṣẹ.*
26 Ní gbogbo àkókò yìí, ọmọdékùnrin náà Sámúẹ́lì ń dàgbà sí i, ó sì túbọ̀ ń rí ojú rere Jèhófà àti ti àwọn èèyàn.+
19 Sámúẹ́lì ń dàgbà sí i, Jèhófà fúnra rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,+ kò sì jẹ́ kí èyíkéyìí nínú gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ láìṣẹ.*