1 Sámúẹ́lì 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbàrà tí Dáfídì bá Sọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ tán, Jónátánì+ àti Dáfídì wá di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́,* Jónátánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara rẹ̀.*+ Òwe 18:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn ọ̀rẹ́ kan wà tí wọ́n ṣe tán láti ṣe ara wọn níkà,+Àmọ́ ọ̀rẹ́ kan wà tó ń fà mọ́ni ju ọmọ ìyá lọ.+
18 Gbàrà tí Dáfídì bá Sọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ tán, Jónátánì+ àti Dáfídì wá di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́,* Jónátánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara rẹ̀.*+
24 Àwọn ọ̀rẹ́ kan wà tí wọ́n ṣe tán láti ṣe ara wọn níkà,+Àmọ́ ọ̀rẹ́ kan wà tó ń fà mọ́ni ju ọmọ ìyá lọ.+