1 Sámúẹ́lì 17:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Dáfídì ki ọwọ́ bọ inú àpò rẹ̀, ó mú òkúta kan níbẹ̀, ó sì ta á. Ó ba iwájú orí Filísínì náà, òkúta náà wọ orí rẹ̀ lọ, ó sì ṣubú ní ìdojúbolẹ̀.+
49 Dáfídì ki ọwọ́ bọ inú àpò rẹ̀, ó mú òkúta kan níbẹ̀, ó sì ta á. Ó ba iwájú orí Filísínì náà, òkúta náà wọ orí rẹ̀ lọ, ó sì ṣubú ní ìdojúbolẹ̀.+