2 Sámúẹ́lì 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ ṣá, ọba ṣàánú Méfíbóṣétì+ ọmọ Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù nítorí ìbúra tó wáyé níwájú Jèhófà láàárín Dáfídì àti Jónátánì+ ọmọ Sọ́ọ̀lù.
7 Àmọ́ ṣá, ọba ṣàánú Méfíbóṣétì+ ọmọ Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù nítorí ìbúra tó wáyé níwájú Jèhófà láàárín Dáfídì àti Jónátánì+ ọmọ Sọ́ọ̀lù.