-
1 Sámúẹ́lì 20:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Dáfídì wá sọ fún Jónátánì pé: “Ọ̀la ni òṣùpá tuntun,+ wọ́n á sì máa retí pé kí n jókòó pẹ̀lú ọba láti jẹun. Ní báyìí, jẹ́ kí n lọ fara pa mọ́ sínú pápá títí di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹta.
-