-
1 Sámúẹ́lì 22:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ó tún fi idà ṣá àwọn ará Nóbù+ tó jẹ́ ìlú àwọn àlùfáà balẹ̀; ó pa ọkùnrin àti obìnrin, ọmọdé àti ọmọ jòjòló, akọ màlúù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ àti àgùntàn, gbogbo wọn ni ó fi idà pa.
-