1 Sámúẹ́lì 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, Sọ́ọ̀lù mú un kúrò níwájú rẹ̀, ó sì yàn án ṣe olórí ẹgbẹ̀rún, Dáfídì sì máa ń kó àwọn ọmọ ogun náà lọ sójú ogun.*+
13 Torí náà, Sọ́ọ̀lù mú un kúrò níwájú rẹ̀, ó sì yàn án ṣe olórí ẹgbẹ̀rún, Dáfídì sì máa ń kó àwọn ọmọ ogun náà lọ sójú ogun.*+