-
1 Sámúẹ́lì 18:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ lọ, wọ́n sì pa igba (200) lára àwọn ọkùnrin Filísínì, Dáfídì kó gbogbo adọ̀dọ́ wọn wá fún ọba, kó lè bá ọba dána. Torí náà, Sọ́ọ̀lù fún un ní Míkálì ọmọ rẹ̀ láti fi ṣe aya.+
-