1 Àwọn Ọba 2:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ọba sọ fún àlùfáà Ábíátárì+ pé: “Lọ sí ilẹ̀ rẹ ní Ánátótì!+ Ikú tọ́ sí ọ, àmọ́ mi ò ní pa ọ́ lónìí yìí, torí pé o gbé Àpótí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ níwájú Dáfídì bàbá mi+ àti nítorí pé o jẹ nínú gbogbo ìyà tó jẹ bàbá mi.”+
26 Ọba sọ fún àlùfáà Ábíátárì+ pé: “Lọ sí ilẹ̀ rẹ ní Ánátótì!+ Ikú tọ́ sí ọ, àmọ́ mi ò ní pa ọ́ lónìí yìí, torí pé o gbé Àpótí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ níwájú Dáfídì bàbá mi+ àti nítorí pé o jẹ nínú gbogbo ìyà tó jẹ bàbá mi.”+