1 Sámúẹ́lì 23:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nítorí náà, wọ́n ṣáájú Sọ́ọ̀lù lọ sí Sífù,+ nígbà tí Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ ṣì wà ní aginjù Máónì+ ní Árábà+ ní apá gúúsù Jéṣímónì.
24 Nítorí náà, wọ́n ṣáájú Sọ́ọ̀lù lọ sí Sífù,+ nígbà tí Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ ṣì wà ní aginjù Máónì+ ní Árábà+ ní apá gúúsù Jéṣímónì.