-
1 Sámúẹ́lì 26:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Sọ́ọ̀lù bá dìde, òun àti ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) àṣàyàn ọkùnrin ní Ísírẹ́lì sì lọ sí aginjù Sífù láti wá Dáfídì nínú aginjù náà.+
-