1 Sámúẹ́lì 23:28, 29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ni Sọ́ọ̀lù ò bá lépa Dáfídì mọ́,+ ó sì lọ gbéjà ko àwọn Filísínì. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi pe ibẹ̀ ní Àpáta Ìpínyà. 29 Lẹ́yìn náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀, ó sì dúró sí àwọn ibi tó ṣòroó dé ní Ẹ́ń-gédì.+
28 Ni Sọ́ọ̀lù ò bá lépa Dáfídì mọ́,+ ó sì lọ gbéjà ko àwọn Filísínì. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi pe ibẹ̀ ní Àpáta Ìpínyà. 29 Lẹ́yìn náà, Dáfídì kúrò níbẹ̀, ó sì dúró sí àwọn ibi tó ṣòroó dé ní Ẹ́ń-gédì.+