-
1 Sámúẹ́lì 26:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Kí olúwa mi ọba jọ̀wọ́ fetí sí ọ̀rọ̀ ìránṣẹ́ rẹ̀: Tó bá jẹ́ pé Jèhófà ni ó fi sí ọ lọ́kàn láti máa lépa mi, kí ó gba* ọrẹ ọkà mi. Àmọ́ tó bá jẹ́ pé àwọn èèyàn ló fi sí ọ lọ́kàn,+ ègún ni fún wọn níwájú Jèhófà, torí pé wọ́n ti lé mi jáde lónìí, kí n má bàa ní ìpín nínú ogún Jèhófà,+ wọ́n ń sọ pé, ‘Lọ, kí o sì sin àwọn ọlọ́run míì!’
-