ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 24:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àwọn ọkùnrin Dáfídì sọ fún un pé: “Ọjọ́ yìí ni Jèhófà sọ fún ọ nípa rẹ̀ pé, ‘Wò ó! Màá fi ọ̀tá rẹ lé ọ lọ́wọ́,+ o lè ṣe ohunkóhun tó bá dára ní ojú rẹ sí i.’” Torí náà, Dáfídì dìde, ó sì rọra gé etí aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá tí Sọ́ọ̀lù wọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́