1 Sámúẹ́lì 26:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jèhófà ló máa san òdodo àti ìṣòtítọ́ kálukú+ pa dà fún un, torí pé Jèhófà fi ọ́ lé mi lọ́wọ́ lónìí, àmọ́ mi ò fẹ́ gbé ọwọ́ mi sókè sí ẹni àmì òróró Jèhófà.+
23 Jèhófà ló máa san òdodo àti ìṣòtítọ́ kálukú+ pa dà fún un, torí pé Jèhófà fi ọ́ lé mi lọ́wọ́ lónìí, àmọ́ mi ò fẹ́ gbé ọwọ́ mi sókè sí ẹni àmì òróró Jèhófà.+