1 Sámúẹ́lì 25:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Orúkọ ọkùnrin náà ni Nábálì,+ ìyàwó rẹ̀ sì ń jẹ́ Ábígẹ́lì.+ Ìyàwó yìí ní òye, ó sì rẹwà, ṣùgbọ́n ọkọ rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ Kélẹ́bù+ le, ìwà rẹ̀ sì burú.+
3 Orúkọ ọkùnrin náà ni Nábálì,+ ìyàwó rẹ̀ sì ń jẹ́ Ábígẹ́lì.+ Ìyàwó yìí ní òye, ó sì rẹwà, ṣùgbọ́n ọkọ rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ Kélẹ́bù+ le, ìwà rẹ̀ sì burú.+