1 Sámúẹ́lì 25:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo gbọ́ pé ò ń rẹ́ irun àwọn àgùntàn rẹ. Nígbà tí àwọn olùṣọ́ àgùntàn rẹ wà lọ́dọ̀ wa, a ò pa wọ́n lára,+ kò sì sí nǹkan wọn tó sọ nù ní gbogbo ìgbà tí wọ́n fi wà ní Kámẹ́lì.
7 Mo gbọ́ pé ò ń rẹ́ irun àwọn àgùntàn rẹ. Nígbà tí àwọn olùṣọ́ àgùntàn rẹ wà lọ́dọ̀ wa, a ò pa wọ́n lára,+ kò sì sí nǹkan wọn tó sọ nù ní gbogbo ìgbà tí wọ́n fi wà ní Kámẹ́lì.