-
1 Sámúẹ́lì 24:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Lẹ́yìn náà, Dáfídì dìde, ó jáde kúrò nínú ihò náà, ó sì nahùn pe Sọ́ọ̀lù, o ní: “Olúwa mi ọba!”+ Nígbà tí Sọ́ọ̀lù bojú wẹ̀yìn, Dáfídì tẹrí ba, ó sì dọ̀bálẹ̀.
-
-
1 Sámúẹ́lì 24:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Bí Dáfídì ṣe parí ọ̀rọ̀ tó sọ fún Sọ́ọ̀lù yìí, Sọ́ọ̀lù sọ pé: “Ṣé ohùn rẹ nìyí, Dáfídì ọmọ mi?”+ Sọ́ọ̀lù sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún kíkankíkan.
-