-
1 Sámúẹ́lì 29:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àwọn alákòóso Filísínì ń kọjá lọ pẹ̀lú ọgọ́rọ̀ọ̀rún àti ẹgbẹẹgbẹ̀rún wọn, Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ sì ń rìn bọ̀ lẹ́yìn pẹ̀lú Ákíṣì.+
-