-
1 Sámúẹ́lì 14:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Sọ́ọ̀lù béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run pé: “Ṣé kí n lọ bá àwọn Filísínì?+ Ṣé wàá fi wọ́n lé Ísírẹ́lì lọ́wọ́?” Àmọ́ Ọlọ́run kò dá a lóhùn ní ọjọ́ yẹn.
-