ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 28:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Nígbà yẹn, àwọn Filísínì kó àwọn ọmọ ogun wọn jọ láti bá Ísírẹ́lì jà.+ Nítorí náà, Ákíṣì sọ fún Dáfídì pé: “Ṣé o mọ̀ pé ìwọ àti àwọn ọkùnrin rẹ máa bá mi lọ jagun?”+

  • 1 Sámúẹ́lì 31:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Nígbà náà, àwọn Filísínì ń bá Ísírẹ́lì jà.+ Àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì sá kúrò níwájú àwọn Filísínì, ọ̀pọ̀ lára wọn sì kú sórí Òkè Gíbóà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́