-
1 Sámúẹ́lì 23:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ní kíá, Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ dìde, nǹkan bí ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ni wọ́n,+ wọ́n kúrò ní Kéílà, wọ́n sì ń lọ sí ibikíbi tí wọ́n bá lè lọ. Nígbà tí Sọ́ọ̀lù gbọ́ pé Dáfídì ti sá kúrò ní Kéílà, kò wá a lọ mọ́.
-