-
1 Sámúẹ́lì 30:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Nígbà náà, Dáfídì dé ọ̀dọ̀ igba (200) ọkùnrin tó rẹ̀ débi pé wọn ò lè tẹ̀ lé Dáfídì, tí wọ́n sì dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ Àfonífojì Bésórì,+ wọ́n jáde wá pàdé Dáfídì àti àwọn èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀. Nígbà tí Dáfídì sún mọ́ àwọn ọkùnrin náà, ó béèrè àlàáfíà wọn.
-