1 Sámúẹ́lì 30:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lépa àwọn jàǹdùkú* yìí? Ṣé màá lé wọn bá?” Ó sọ fún un pé: “Lépa wọn, torí ó dájú pé wàá lé wọn bá, wàá sì gba àwọn èèyàn rẹ pa dà.”+
8 Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lépa àwọn jàǹdùkú* yìí? Ṣé màá lé wọn bá?” Ó sọ fún un pé: “Lépa wọn, torí ó dájú pé wàá lé wọn bá, wàá sì gba àwọn èèyàn rẹ pa dà.”+