-
2 Sámúẹ́lì 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Dáfídì sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Báwo ni ọ̀hún ṣe rí? Jọ̀ọ́, sọ fún mi.” Ó dáhùn pé: “Àwọn èèyàn ti sá kúrò lójú ogun, ọ̀pọ̀ ló ti ṣubú tí wọ́n sì ti kú. Kódà Sọ́ọ̀lù àti Jónátánì ọmọ rẹ̀ ti kú.”+
-