-
1 Sámúẹ́lì 27:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà náà, Dáfídì sọ fún Ákíṣì pé: “Tí mo bá rí ojú rere rẹ, jẹ́ kí wọ́n fún mi ní àyè nínú ọ̀kan lára àwọn ìlú tó wà ní ìgbèríko, kí n lè máa gbé ibẹ̀. Kí nìdí tí ìránṣẹ́ rẹ á fi máa bá ọ gbé nínú ìlú ọba?” 6 Torí náà, Ákíṣì fún un ní Síkílágì+ ní ọjọ́ yẹn. Ìdí nìyẹn tí Síkílágì fi jẹ́ ti àwọn ọba Júdà títí di òní yìí.
-