2 Sámúẹ́lì 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọba ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Ṣé ẹnì kankan ṣì kù ní ilé Sọ́ọ̀lù tí mo lè nawọ́ ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í yẹ̀ sí?” Síbà dá ọba lóhùn pé: “Ọmọkùnrin Jónátánì kan ṣì wà; ó rọ ní ẹsẹ̀ méjèèjì.”*+
3 Ọba ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Ṣé ẹnì kankan ṣì kù ní ilé Sọ́ọ̀lù tí mo lè nawọ́ ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í yẹ̀ sí?” Síbà dá ọba lóhùn pé: “Ọmọkùnrin Jónátánì kan ṣì wà; ó rọ ní ẹsẹ̀ méjèèjì.”*+