2 Àwọn ọkùnrin méjì kan wà tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn akónilẹ́rù tó jẹ́ ti ọmọ Sọ́ọ̀lù: ọ̀kan ń jẹ́ Báánà, èkejì sì ń jẹ́ Rékábù. Ọmọ Rímónì ará Béérótì ni wọ́n, wọ́n wá láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì. (Nítorí pé tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n máa ń ka Béérótì+ mọ́ ara Bẹ́ńjámínì.