Jóṣúà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí oòrùn ṣe dúró sójú kan nìyẹn, òṣùpá ò sì kúrò títí orílẹ̀-èdè náà fi gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀. Ṣebí wọ́n kọ ọ́ sínú ìwé Jáṣárì?+ Oòrùn dúró sójú kan ní àárín ojú ọ̀run, kò sì tètè wọ̀ fún nǹkan bí odindi ọjọ́ kan.
13 Bí oòrùn ṣe dúró sójú kan nìyẹn, òṣùpá ò sì kúrò títí orílẹ̀-èdè náà fi gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀. Ṣebí wọ́n kọ ọ́ sínú ìwé Jáṣárì?+ Oòrùn dúró sójú kan ní àárín ojú ọ̀run, kò sì tètè wọ̀ fún nǹkan bí odindi ọjọ́ kan.