2 Sámúẹ́lì 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Lẹ́yìn náà, Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lọ sínú ọ̀kan lára àwọn ìlú Júdà?” Jèhófà sọ fún un pé: “Lọ.” Dáfídì bá béèrè pé: “Ibo ni kí n lọ?” Ó fèsì pé: “Lọ sí Hébúrónì.”+ 2 Sámúẹ́lì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àkókò* tí Dáfídì fi jọba ní Hébúrónì lórí ilé Júdà jẹ́ ọdún méje àti oṣù mẹ́fà.+ 1 Kíróníkà 12:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Iye àwọn olórí ọmọ ogun tó ti gbára dì tó wá sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hébúrónì+ láti fi í jọba ní ipò Sọ́ọ̀lù nìyí gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Jèhófà pa.+
2 Lẹ́yìn náà, Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lọ sínú ọ̀kan lára àwọn ìlú Júdà?” Jèhófà sọ fún un pé: “Lọ.” Dáfídì bá béèrè pé: “Ibo ni kí n lọ?” Ó fèsì pé: “Lọ sí Hébúrónì.”+
23 Iye àwọn olórí ọmọ ogun tó ti gbára dì tó wá sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hébúrónì+ láti fi í jọba ní ipò Sọ́ọ̀lù nìyí gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Jèhófà pa.+