-
Léfítíkù 27:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 “‘Tí ẹnì kan bá ya apá kan lára ilẹ̀ rẹ̀ sí mímọ́ fún Jèhófà, iye irúgbìn tí wọ́n máa fún sínú rẹ̀ ni wọ́n á fi díwọ̀n iye tí wọ́n máa dá lé e: ọkà bálì tó kún òṣùwọ̀n hómérì* kan máa jẹ́ àádọ́ta (50) ṣékélì fàdákà.
-