1 Kíróníkà 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Gbàrà tí Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé inú ilé* rẹ̀, ó sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì+ kọ́ nígbà tí àpótí májẹ̀mú Jèhófà wà lábẹ́ àwọn aṣọ àgọ́.”+
17 Gbàrà tí Dáfídì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé inú ilé* rẹ̀, ó sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì+ kọ́ nígbà tí àpótí májẹ̀mú Jèhófà wà lábẹ́ àwọn aṣọ àgọ́.”+