Diutarónómì 10:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òun ni Ẹni tí wàá máa yìn.+ Òun ni Ọlọ́run rẹ, tó ṣe gbogbo ohun àgbàyanu àtàwọn ohun tó ń dẹ́rù bani yìí fún ọ, tí o sì fi ojú ara rẹ rí i.+
21 Òun ni Ẹni tí wàá máa yìn.+ Òun ni Ọlọ́run rẹ, tó ṣe gbogbo ohun àgbàyanu àtàwọn ohun tó ń dẹ́rù bani yìí fún ọ, tí o sì fi ojú ara rẹ rí i.+