1 Kíróníkà 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà tó yá, Dáfídì ṣẹ́gun àwọn Filísínì, ó borí wọn, Dáfídì sì gba Gátì+ àti àwọn àrọko* rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn Filísínì.+
18 Nígbà tó yá, Dáfídì ṣẹ́gun àwọn Filísínì, ó borí wọn, Dáfídì sì gba Gátì+ àti àwọn àrọko* rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn Filísínì.+